Font Size
Romu 3:31
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Romu 3:31
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
31 (A)Àwa ha ń sọ òfin dasán nípa ìgbàgbọ́ bí? Kí a má rí i: ṣùgbọ́n a ń fi òfin múlẹ̀.
Read full chapter
Galatia 5:16
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Galatia 5:16
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìyè nípa ti ẹ̀mí
16 Ǹjẹ́ mo ní, Ẹ máa rìn nípa ti Ẹ̀mí, ẹ̀yin kì yóò sì mú ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ti ara ṣẹ.
Read full chapter
Galatia 5:25
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Galatia 5:25
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
25 Bí àwa bá wà láààyè sípa ti Ẹ̀mí, ẹ jẹ́ kí a sì máa rìn nípa ti Ẹ̀mí.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.