Font Size
Luku 9:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Luku 9:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Jesu bọ́ ẹgbẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n ènìyàn
10 (A)Nígbà tí àwọn aposteli sì padà dé, wọ́n ròyìn ohun gbogbo fún un tí wọ́n ti ṣe. Ó sì mú wọn, lọ sí apá kan níbi tí a ń pè ní Betisaida.
Read full chapter
Marku 3:20
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Marku 3:20
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Jesu àti Beelsebulu
20 (A)Nígbà náà ni Jesu sì wọ inú ilé kan, àwọn èrò sì tún kórajọ, tó bẹ́ẹ̀ tí Òun àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ kò rí ààyè láti jẹun.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.