Font Size
Johanu 3:13
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 3:13
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
13 (A)Kò sì ṣí ẹni tí ó gòkè re ọ̀run bí kò ṣe ẹni tí ó ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ wá, Ọmọ Ènìyàn tí ń bẹ ní ọ̀run.
Read full chapter
Johanu 8:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 8:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
23 (A)Ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ̀yin ti ìsàlẹ̀ wá; èmi ti òkè wá; ẹ̀yin jẹ́ ti ayé yìí; èmi kì í ṣe ti ayé yìí.
Read full chapter
1 Johanu 4:5
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Johanu 4:5
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
5 (A)Tí ayé ni wọ́n, nítorí náà ni wọn ṣe ń sọ̀rọ̀ bí ẹni ti ayé, ayé sì ń gbọ́ tí wọn.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.